Hymn 199 - (Yor) - Iwo To Fe Wa
Verse 1
Iwo to fe wa la o ma sin titi Oluwa olorewa Iwo to nsowa n'nu idanwo aye Mimo, logo ola re
Verse 2
Iwo to nsure s'ohun t'a gbinsaye T'aiye fi nrohun je o Awon to mura lato ma s'oto Won tun nyo n'nu is Re
Chorus
Baba iwol'a o ma sin Baba iwol'ao ma bo Iwo to fewa l'a o ma sin titi Mimo l'ogo ola re
Verse 3
Iwo to nf'agan l'omo to npe ranse Ninu ola Re to ga Eni t'o ti s'alaileso si dupe Fun'se ogo ola Re
Verse 4
Eni t'ebi npa le ri ayo ninu Agbara nla Re to ga Awon to ti nwoju Re fun anu Won tun nyo n'nu ise Re
Verse 5
F'alafia Re fun ijo Re l'aye K'ore-ofe Re ma ga K'awon eni T'ire ko ma yo titi Ninu ogo ise Re
